Ojutoleyorubatv

Ojutoleyorubatv what you need is information we give the best and motivation

10/06/2025

The history of grate African beyond your imagination

06/06/2025

MASSAI TRIBE IN KENYA VERY MYSTERIOUS TRIBE

05/02/2025

Fun ayajo ololufe February 16 ni yi o waye

ALÁFIN O KOSE RI FIN NI NKAN BI ỌDUN 1300bc sẹyin ni ilu ỌYỌ tiwa ilu ọyọ jubi ase ni lèro lọ, ilu ọyọ tobi pupọ debi wi...
17/01/2025

ALÁFIN O KOSE RI FIN
NI NKAN BI ỌDUN 1300bc sẹyin ni ilu ỌYỌ tiwa
ilu ọyọ jubi ase ni lèro lọ, ilu ọyọ tobi pupọ debi wipe ALAFIN ỌYỌ pa asẹ di ilu GHANA, TOGO T**I DE BỌKINAFASO.
gbogbo awọn ilu yii ni wọn san isakọlẹ fun ALAFIN ỌYỌ....

ỌRANMIYAN ni o tẹ ilu ỌYỌ bẹsini ọranmiyan jẹ ọmọ ODUDUWA awọn miran n' peni ọmọ ọmọ ODUDUWA eyi owu kojẹ ọmọ ODUDUWA sha ni ỌRANMIYAN JẸ, ỌRANMIYAN kuro ni ile ifẹ lẹyin ọpọlọpọ ọdun, jagun jagun ni ỌRANMIYAN jẹ osi ni ọpọlọpọ ọmọ ogun..ITAN ORANMIYAN BỌ LỌJỌ WAJU ẸMA BINU...

lẹyin ti ọramiyan di"" ỌBA NILU ỌYỌ ni
n'kan bi ọdun 1300 si ọdun 1210

AJAKA jẹ ỌBA ỌYỌ ni ọdun 1242

SANGO jẹ ỌBA ỌYỌ ni ọdun 1252

AGANJUSỌLA jẹ ỌBA ỌYỌ ni ọdun 1277

ọmọ bibi inu AJAKA ni AGANJUSỌLA jẹ

KORI jẹ ỌBA ỌYỌ ni ọdun 1340 KORI jẹ ọmọ ọmọ AGUNJUSỌLA
ọmọde ni kori jẹ ni gba ti o jẹ ọba ỌYỌ nigba ti baba rẹ ku

OLUASO jẹ ỌBA ỌYỌ ni ọdun 1401 ọmọ bibi inu KORI ni OLUASO jẹ

OLUASO jẹ ọmọ ọba to rẹwa pupọ gbogbo ọmọgé ilu lowu ki wọn jẹ iyawo OLUASO, oluso fẹ iyawo pupọ bẹni osi ọpọlọpọ ọmọ ti alepe kika wọn ọgọrun (100) ati jubẹ lọ.

ONIGBOJI jẹ ỌBA ỌYỌ ni ọdun 1490-1542 asiko ọba onigboji yii ni awọn NUPE gbogun wọ ilu ọyọ ti wọn si fi ogun fọ ọyọ gba na, wọn lewọn kuro ni gbogbo agbegbe na.
😄😄😄😄😄😄 ma tẹsi waju ni apa keji ỌBA ILU ỌYỌ MỌLAFIN OJO PASẸKẸRE MỌDE ỌMỌ ATIBA....

BAWO NI ỌRỌ ATIBA SEJẸ NILU ỌYỌ
TANI WỌN PENI (BASỌRUN JA)
comment yin ati like yin sepataki simi pupọ.... ẹbami share ẹẹẹ🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏

09/01/2025

YORUBA DUN PUPỌ... lowe lowe nilu agidigbo ọlọgbọn lonjo bẹ ọmọran lomọ ooo let listing to this again Itan Yoruba YORUBA SINGLE FATHER AND SINGLE MOTHER GROUP Onu Africa OYO

ITAN BASỌRUN OGUNMỌLA apa kẹrin4               ẹdarapọ mo mi lori whatsapp group ojutoleyorubatv fun awon itan,asa ati ọ...
29/12/2024

ITAN BASỌRUN OGUNMỌLA apa kẹrin4
ẹdarapọ mo mi lori whatsapp group ojutoleyorubatv fun awon itan,asa ati ọrọ agba ẹ follow link yii👉 https://chat.whatsapp.com/LdT54u2dUO39r2clsOlTCH

Moti sọ fun wa lati apa kini t**i de apa kẹta iru eniyan ti ogunmọla jẹ, ati bi ogunmọla se wọ ilu ibadan wa.
moti sọfun wa pe ọpọlọpọ awọn alagbara ni ogunmọla ba ni ilu ibadan nitori wipe ilu awọn jagun jagun ni ibadan jẹ....
IBADAN BÉRÉ KO TO WỌ
IBADAN KI I BA NI SỌRẸ I LỌ S'OGUN IJA IGBORO NI ARUN IBADAN💪💪💪

ni asiko ti a 'n' wiyi ogunmọla ki se jagun jagun tara tara oo sugbọn IDIFALA ATI OLOGUN ni ogumọla jẹ
ogunmọla ki i bẹru, ogunmọla ni aya bi kiniun, ko si ẹni ti ogunmọla ko le woju ẹ😏😏😏
ẸMABAMI BỌ👇
ogunmọla lẹyin igba ti okuro lọdọ IBA OLUYỌLE ati ỌDẸRINLỌ hmmm
otun pada lọ ba IBA OLULỌLE wipe ki wọn jọ wọ ki wọn fun ohun ni inu igbo ti o wa oke iwaju ile IBA ki ohun ti awọn ọmọ ti iyawo ki awọn pajọ sibẹ.....
IBA OLUYỌLE wi fun ogunmọla wipe haa awọn ẹran ko abija ni wọn wa lori oke na......ogunmọla wi fun IBA OLUYỌLE wipe, kosi ewu loko afi jiri jiri aparo hmmmm

bayi mi IBA OLUYỌLE yọ n da fun ogunmọla lati gbe ori oke na ati awọn ọmọ rẹ
ogunmọla pa gbogbo awọn ẹrako buruku ti wọn wa lori oke na, osijẹ ohun iyalẹnu fun awọn olugbe ibadan patapata...... ori oke yi ni wọn n pe ni (oke MỌPO) loni😊😊

ogunmọla bẹrẹ si ni DIFA fun awọn jagun jagun kọkan ni ibadan
bi wọn ba n lọsi oju ogun, ogunmọla yi o bawọn DIFA yi o si se ọpọlọpọ o ogun fun awọn akọni ti wọn n lọsi oju ogun💪💪💪

ogunmọla pinnu ni ọjọ kan wipe haa haa gbogbo awọn ti ohun se o ogun fun ti wọn si n lọsi oju o ogun ti wọn ko ẹru bọ wa sile yii (ẹni ogunmọla gan le seju bẹ lọ)
bayi ni ogunmọla pinu lati mọ darapọ mọ awọn ọmọ o ogun IBADAN ni asiko ti wọn ba n mura o ogun💪💪💪

kini ogbe ogunmọla de ilu ijaye ni akọkọ ti ọ wọ KUNRUNMI fi tẹ ogunmọla
kini ogunmọla se fun iyawọ KUNRUNMI ti wọn fi un fun ni eeru jẹ😃😃
bawo ni ogunmọla se bọ lọwọ KUNRUNMI ijaye.
ẸPADEMI NI APA KARUN ITAN OGUNMỌLA
FUN IBERE IKAN SIMI LORI WHATSAPP +2347056532942 Ojutole

ITAN BASỌRUN OGUNMỌLA apa kẹta 3 Moti sọ fun wa iru eniyan ti ogunmọla jẹmoti sọ ilu ti abi ogunmọla si fun wa ni apa ki...
27/12/2024

ITAN BASỌRUN OGUNMỌLA
apa kẹta 3
Moti sọ fun wa iru eniyan ti ogunmọla jẹ
moti sọ ilu ti abi ogunmọla si fun wa ni apa kini ati apa keji
moti sọ fun wa pe ogunmọla bi ọmọ mẹta ti mo si da orukọ awọn mẹtẹta 👇
ỌMỌSA jẹ ọmọ obirin akọbi
ỌSUN ati ALỌRI jẹ ọmọ kunrin
akọni alagbara ni awọn ọmọ ogunmọla jẹ.......💪💪💪 ỌMỌSA jẹ alagbara obirin bi ọkunrin
ẸMABAMI BỌ👇

ẸBAMI FOLLOW PAGE YII ẸJỌWỌ 🙏🙏WỌN TI HACK EYI TI A NLO TẸLẸ

KINI ITUNMỌ OGUNMỌLA OLODOGBO KẸRI LOJU OGUN
awọn miran sọ wipe olododo keri loju ogun ni sugbọn kori bẹ ẹ😃😃

ogunmọla ki i dajọ
ogunmọla ki i se balẹ
sugbọn ohun kan wa ti wọn n peni ODOGBO👈
ODOGBO yi da gẹgẹ bi (ẹwọn- CHAIN) odogbo yi ni ogunmọla ma
n' muda ni lọsi oju ogun 💪💪💪 ti ogunmọla bati n fi odogbo yi i💫💫💫💫💫 didun ti o ma 'n' dun na ni kẹri kẹri .......
ni wọn se ma 'n' ki oriki ogunmọla pe OLODOGBO KẸRÍRI KẸRIRI LOJU OGUN💪💪💪ỌWỌ SOKOTO KẸNBẸ RE BI IJA🙌🙌🙌

ni ọjọ ti ogunmọla wọ Ibadan wa
ogunmọla ba awọn akọni alagbara ni ibadan
ogunmọla ba ỌDẸRINLỌ NI IBADAN
ogunmọla ba IBA OLUYỌLE NI IBADAN
ogunmọla ba IBIKUNLE NI IBADAN
ogunmọla ba IBIKUNLE NI IBADAN
ati ọpọlọpọ awọn akọni alagbara ni IBADAN.
Ni igba ti ogunmọla wọ ilu ibadan, ogunmọla lọ ọ ile OLUYỌLE lati lọ ki oluyọle gẹgẹ bi alejo ti ọsẹsẹ wọ ilu wa, oluyọle gba ni alejo sugbọn ogunmọla kọ lati wa ni agbala OLUYỌLE, nitori wipe awọn ẸRU ni wọn ma 'n' gbe ni agbala... ogunmọla kọ lati wa ni agbala oluyọle👇👇

ogunmọla tun lọsi ọdọ ỌDERINLỌ sugbọn ohun ti OLUYỌLE sọ fun na ni ỌDẸRINLỌ na sọ fun ogunmọla, ni tori wipe wọn mọ wipe OLOGUN ATI ONI IFA ni ogunmọla jẹ.....
ẹdarapọ mọ mi lori whatssap group yii link 👉https://chat.whatsapp.com/LdT54u2dUO39r2clsOlTCH

nibọ wa ni ogunmọla gbe ni bo ni ogunmọla sun ni IBADAN
niki o sọ ogunmọla di alagbara ni IBADAN
epade mi ni apa kẹrin itan ogunmọla whatssap+2347056532942

ITAN BASỌRUN OGUNMỌLAapakeji 2moti sọfun wa wipe ọmọ bibi ilu kan ti wọn peni FESSU ni orilẹ IWO ni OGUNMỌLA moti sọfun ...
23/12/2024

ITAN BASỌRUN OGUNMỌLA
apakeji 2
moti sọfun wa wipe ọmọ bibi ilu kan ti wọn peni FESSU ni orilẹ IWO ni OGUNMỌLA
moti sọfun wa wipe ọmọ babalawo ti o gbọ ifa yaranyanran ni OGUNMỌLA
moti sọfun wa wipe lati nkan bi ọmọ ọdun mẹwa ni OGUNMỌLA ti mọ nipa dida a ifa👇

ẹbami follow page tuntun yi pada 😭 😭wọn ti hack eyi ti a nlo tẹlẹ
ẹ tun n le darapọ mọmi lori WHATSAP GROUP link yii👉 https://chat.whatsapp.com/LdT54u2dUO39r2clsOlTCH

Ninu oriki ogunmọla👇
ỌGUNMỌLA ỌWỌ Ọ SOKOTO KẸNBẸ REBI IJA 💪
OGUNMỌLA "OLODODO" KẸRI KẸRI LOJU OGUN💪
OGUNMỌLA KAN IBADAN KAN💪
ỌPẸ IJA YÉ LABAPÈ KOWA ROYIN OGUN OGUNMỌLA, KI OLE GBỌ Ọ BI INA SE UN RAN LOKO HMMM
Ogunmọla jagun jagun alagbara💪

ogunmọla bi ọmọ mẹta, okunrin meji ati ọmọ birin ọkan......
orukọ awọn ọmọ ogunmọla ni👇
1 ỌMỌSA obirin ni ohun si ni akọbi OGUNMỌLA
2 ILỌRI ọmọ kunrin ni ati
3 ỌSUN ọmọ kunrin ni

gbogbo awọn ọmọ OGUNMỌLA MẸTẸTA yi akọni alagbara ni wọn jẹ

ỌMỌSA mi alagbara obinrin jagun jagun ti awọn akọni ọkunrin n wari fun, alagbara nla ti awọn IJẸBU n pe ni AJẸNBIRIN loju ogun
ỌMỌSA ni akọni obinrin ti ko si iru alagbara rẹ nilẹ Yoruba

kini itunmọ ogunmọla olododo kẹri loju ogun. Se ododo ni abi odogbo?

Tani ana ogunmọla ninu itan t**i di oni..... ẹpademi ni apa kẹta itan basọrun ogunmọla.
ẹbami follow page yii ẹ comment ki ẹ si bami share ẹ🙏🙏🙏🙏 layọ la o pade ni apa kẹta itan sẹsẹ bẹrẹ.

ITAN BASỌRUN OGUNMỌLABasọrun alagbara jajunjagun ni ỌGUNMỌLAọpẹ ijaye lole royin o ogun ogunmọla   ogunmọla ni lagbara t...
20/12/2024

ITAN BASỌRUN OGUNMỌLA
Basọrun alagbara jajunjagun ni ỌGUNMỌLA
ọpẹ ijaye lole royin o ogun ogunmọla
ogunmọla ni lagbara ti awọn ilu bi
EKITI ,IJAYE, IJẸBU kole gbagbe ninu itan
ilu kan ni orilẹ ilu iwo ti orukọ ilu na n jẹ ifeesu ni wọn bi OGUNMỌLA si
👇👇👇👇 follow lori whatssap ojutoleyorubatv link yii👉 https://chat.whatsapp.com/LdT54u2dUO39r2clsOlTCH

OGUNMỌLA jẹ ọmọ babalawo ti o gbọ ifa yanran yanran
OGUNMỌLA jẹ kinkanju ọmọ, lati nkan bi ọmọ ọdun mẹwa (10Years) ni ogunmọla ti mọ nipa ifa daradara ti o sile difa fun eniyan gẹgẹ bi isẹ ti o ba lọwọ barẹ hmmmm
kini o sọ ogunmọla di jagun jagun alagbara
kini o gbe ogunmọla de IJAYE ti aarẹ kunrunmi fi demọ lẹ ti wọn si fun ni eri ati eru u jẹ ẹ.
ẹpademi ni apa keji itan BASỌRUN OGUNMỌLA

10/12/2024

Itan Ilu Ita Gbangba. Hmmm

Address

Ibadan
Ibadan

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ojutoleyorubatv posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share